Overview
Akekoo yoo le so ise ti oro oruko ati arọ́pò oruko n se ninu gbolohun.
What you'll learn
- Olùwa:
- • Igi wo
- • Mo lo si oja
- Abo fun oro ise:
- • Olu ko iwe
- • Baba na an
- Abo fun oro atokun:
- • Sade lo si oja
- Eyan fun oro oruko miiran
- • Baba arugbo da?
- • Oga mi ko ile.