Overview
Akekoo yoo le:
So ohun ti aroko je.
Daruko die ninu awon ami aroko.
What you'll learn
- Ohun ti aroko je (ona ìbánisọ̀rọ̀ laye atijo ti a le fi we leta kiko lode oni).
- Orisiirisii aroko: aale, aga, itufu, aroko gan-an.
- Bi a se n paroko ni aye atijo.
- Awon ami ìpàrokò ni atijo ati itumo won b.a. owo eyo meta, ikarahun igbin, iye, abbl.
- Aroko ode oni.