Please ensure Javascript is enabled for purposes of website accessibility
SS1 Yoruba Language

Ede: Isori oro

Overview

Akekoo yoo le: Daruko awon isoro oro yorùba; Toka si isori kookan ninu gbolohun. So ise ti okookan n se ninu gbolohun

What you'll learn
  • Isori oro:
  • Oro oruko
  • Oro àròpọ̀ oruko
  • Oro apejuwe
  • Oro atọ́kùn
  • Oro asòpò
  • Àlàyé kikun lori ipo ati ise won ninu gbolohun.