Overview
Akekoo yoo le:
So die nipa ogun yorùba laye àtijo :
• Oruko awon ògun ti won ja
• Awon jagunjagun
• Ohun elo ìjagun.
Anfaani ogun jija
Ona lati dekun ogun abi lati wa alaafia.
What you'll learn
- Ki ni ogun?; ki si ni idi ti o fi maa n waye?
- Ogun yorùba laye atijo:
- • Oruko ogun b.a. jalumi,kiriji, abbl
- • Awon jagunjagun b.a. ibikunle, ogunmola, ogedengbe abbl
- • Ohun elo ogun b.a. ofa,oko,ida, ada, ìbon, oogun.
- Anfaani ogun jija: ona idaabobo ilu eni, lati ko eni leru, abbl.
- Aleebu ogun nipa ose ti o n se:
- • Da ota sile
- • Run ilu
- • Fa iyan, abbl.
- Ona lati dekun ogun jija:
- • Yiyago fun aáwọ̀
- • Nini suuru, ipamora, iwa pele, ikonimora, ife, ibowo fun omolakeji (omoluabi)