Overview
Akekoo yoo le:
Daruko ìsáré ajemesin ati ayéye tabi alaijemesin die
Se alaye ọ̀gangan ipo okòòkan.
What you'll learn
- Kini ìsáré ajemesin ati ajemayeye tabi alaijemesin? (ohun pipe/ofun sise ti a n lo ni idi esin orisa kan ati eyi ti a n lo fun ayéye ti ko je mo esin orisa).
- Ìsáré ajemesin yorùba:
- • Ijala
- • Esa/iwì egungun
- • Iyere ifa
- • Sàngó pipe
- • Esu pipe, abbl
- Ìsáré ajemesin tabi alaijemesin:
- • Rara
- • Ekun iyawo
- • Ègé
- • Alamo, abbl