Overview
Akekoo yoo le:
Salaye eto isomoloruko ni sise-n-tele.
So orisiirisi oruko ti yorùba n so omo won ati idi ti won fi n so omo won bee.
What you'll learn
- Igbagbo yorùba nipa bi oruko se se pataki to (oruko omo ni ijanu omo, oruko a maa ro omo) oruko rere.
- Eto isolomoloruko b.a. lilo ireke, oyin, aadun, abbl fun iware.
- Orisiirisi oruko:
- • Abiso
- • Amutorunwa
- • Oriki
- • Abiku
- • Inagije
- • Idile, abbl.