Overview
Akekoo yoo le:
Salaye lori asà oyun nini ati itoju oyun;
So awon ohun to le dena oyun nini;
So ohun to le fa bibi abiku.
What you'll learn
- Igbagbo yorùba nipa agan, omo bibi ati abiku.
- Awon ti oyun nini wa fun (tokotaya).
- Ona ti a le gba din bibi abiku ku lawujo;
- Orisiirisii jenotaipu eje to wa ati awon to le fera won;
- Aajo lati le tete loyun – anfaani kikora-eni-nijanu nipa ibalopo.
- Bi a se n toju aboyun làtijọ ati lode oni. Atijo :
Oyun dide, Èewo ki aláboyún, aseje, agbo, abbl.
Ode oni:
Ounje asara lóore, Lilo fun itoju ni ile iwosan (ibile/ijoba) abbl.