Overview
Akekoo yoo le:
Ka awon ewi naa ni akadanmoran ati akaye.
So ohun ti won gbádùn ninu ewi kookan ti won ka ati idi ti won fi gbádùn re.
Toka si ewa ede to sùyo ninu awon ewi naa
What you'll learn
- Awon ewi to wa ninu iwe ti a yan.
- Koko oro b.a: Iwa eniyan; Awon eda miiran ti kii se eniyan; koko oro to je mo; oro to n lo lawujo, ikolura esin, Asà, ipo obinrin, Eto iselu, oro aje, Gbogbolomo isako/isabo, Eedi
- Akiyesi: Opón dandan lati yan iwe ewi ti o ni awon akoonu koko oro wonyi
- Ona ede ati isowoloede