Akekoo yoo le: Se ìdámọ̀ awon àbùdá ti yoo maa kiyesii ninu litireso apileko ti o fe se agbeyewo re. Ko oye re nipa awon àbùdá yii láti jiroro nipa / se agbeyewo litireso apileko.