Overview
Akekoo yoo le:
So orisii leta méjì to wa: gbefe àti aigbagbefe.
So ìyàtọ̀ àárín won
Ko orisi leta mejeeji
What you'll learn
- Orisii leta: gbefe àti aigbagbefe
- Ìyàtọ̀ àárín won.
- Ìlapa kiko leta gbefe:
- • Àdíréẹ̀sì
- • Déètì’
- • Kiko oro inu leta ki a si pin in si ègé afò bi oti ye
- • Asokagba/Agbàlọ̀ gbábò/igunle
- Ilapa kiko leta aigbagbefe:
- • Àdíréẹ̀sì
- • Déètì
- • Akole
- • Oro inu leta ti a pin si ègé afo bi o ti ye