Overview
So àbùdá pataki ti o mu ki agbeyewo litireso alohùn yato si ti apileko (ọ̀gangan-ipo).
Darukọ awon abuda ọ̀gangan-ipo.
What you'll learn
- Ògangan-ipo:
- • Ìtumọ̀ re
- • Àbùdá re:
- (a) Akopa (osere/olugbo)
- (b) Akoko isere
- (c) Ibi seré
- (d) Iwulo
- (e) Ohun elo-orin
- (f) Isele
- (g) Ifarafojusoro
- (h) Ìsáré, orin, ijo