Overview
So ohùn ti akotó je.
So ìyàtọ̀ laarin akotó odè oni ati ti atijo.
Se amulo akoto ode oni ninu kiko oro sile
What you'll learn
- Àlàyé ohun ti akotó je
- Afiwe akotó àtijọ àti ti òde onì :
- (i) Faweli:
- Aiye-ayé
- Yio-yó /yóó /yóò
- Enia-eniyan,
- Abbl.
- (ii) Konsonanti:
- Osogbo-Osogbo
- Illa-ìlà
- (iii) Àmì ohùn :
- Ogun -oogun
- Alanu -alaanu
- (iv) Yíyàn òro nidii:
- ẹ,e,ṣ,s – ẹ, ṣ
- (v) Pinpin oro:
- Wipé -wi pe
- Nigbati -nigba ti